Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí . Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Irú kí ni eléyìí báyìí, àfi kí olúwa olódùmarè .
Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí . Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU).
Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU). Ìsèlè burúkú gbáà ní Óní selè ní ojó kewàá osù keje odún 1999 ní ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university nígbà tí èmi oní inú ire sì gba ibè lo. Afrika ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on AJE NIMO FẸẸ!
. AJE NIMO FẸẸ! Ohun aje f’oju miri ẹnu o le sọ; Oju miri to lori ọrọ aje; Owo(business) f’ẹgbin rẹmi lara; Ninu ẹgbin lọla fiṣe ile; Ọrọ kobakungbe inu iṣẹ-aje ni ngbe. Aje ogugu ni sọ; Onisọ iboji o; ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun.
Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun. Arákùnrin kan ni ó so àwon táyà okò tí ó ti bàjé yí di tábìlì aláfé, okùnrin yí tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà. Kí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon ìbeta tí ó rewà yí tí ewà won sì wuni yí se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tó yááyì.
John, Peter àti Jamie Obidiegwu, ìbeta se ayeye ojó ìbí won ní àrà òtò. Ayeye ojó ìbí míràn ni ó jé fún àwon ìbeta tí ó jé okùnrin yí, ohun ayò ni ayeye yí sì jé fún won tí won ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìgbeyàwó alárédè ti DJ consequences àti Olayemisi Williams.
Arákùnrin tí ó ń se isé DJ tí a mò sí DJ consequences àti aya rè Olayemisi Williams ti se ayeye ìgbeyàwó won. A kí tokotayà kú oríre .
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman
Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman. Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Tokunbo Idowu tí ìnagije rè ń jé Tboss, ti se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè ...
Read More »ayangalu Comments Off on Yorùbá mothers ! (Interesting Read)
Yorùbá mothers are the best when it comes to child upbringing. Yorùbá mothers produce the best range of slaps: IGBATI, IFOTI, IGBAJU, IGBARUN IFORUN, IFAKUN, ILADI, ABARA. These slaps will make you think you were adopted. IGBATI will make you ...
Read More »ayangalu Comments Off on What is the Month of July In Yoruba ?
Awoyemi Bamimore Comments Off on Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.
Èèyàn méjì òtòtò ni ó di olóògbé látàrí àgbàrá òjò tí Ó gbé won lo, tí Óní sì pa wón sí gbàgede enu àbáwolé ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè Nìjíríà, Nsukka (UNN). Gégé bí ìròyìn se so àwon olóògbé ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more