Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...
Read More »Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo
NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà ...
Read More »This is Why the Value of Bitcoin, Ethereum, Ripple, NEM & Others Sharply Fell
On June 15, the cryptocurrency market experienced an important market correction as the worthiness of leading cryptocurrencies including Bitcoin, Ethereum, Ripple, Ethereum Classic and NEM sharply fell.In total, the cryptocurrency market lost around ₦5.8 Trn ($16 bln) in market cap, ...
Read More »Laura Ikeji àti Ogbonaya Kanu kí omo tuntun sí inú ìdílé won ní ìlú òyìnbó (u. S).
Omo ìyá Linda Ikeji , Laura Ikeji àti oko rè Ogbonna Kanu kí omo tuntun káàbò sí ìdílé won ní ìlú òyìnbó (U. S). Linda Ikeji kéde ewu omo tuntun náà lórí èro ayélujàra (instagram), níbi tí o ti pín àwòrán ...
Read More »Syrian War Report – June 14, 2017: Govt Forces Break ISIS Defense Lines In Raqqah And Homs Provinces
The Syrian Army Tiger Forces have made a large progress against ISIS terrorists in the province of Raqqah. The Tiger Forces liberated a number of villages, including Jubb Ghanum, Jubb al Abyad, Madakhah, and Bir Inbaj, the Rusafa oil field, ...
Read More »Omo Oba Gwamnishu Harrison, tí won jígbé ,ké pé òun ń fi Nàìjíríà sílè
Olùdarí ilé-isé (CEO) ‘Behind Bar Initiative’, èyí tí ó pín àwòrán ara rè ní ibi tí ó gbé ń sunkún lórí èro ayélujàra (facebook). Ti so àsírí èròńgbà rè láti fi orílè èdè Nàìjíríà sílè lo sí ìlú òyìnbó (U. ...
Read More »Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River
Léyìn tí a gbó èsì ikú tí ó pa Joy Odama akékòó odún kejí (200l) ti ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó wà ní ìpínlè Cross river (university of science and technology (CRUTEC)) èyí tí ó kú ikú kàyééfi léyìn ìgbà ...
Read More »The Putin Interviews – Part 1&2 (English Subtitles)
Continue after the page break fro Part 2
Read More »Nigerians React After CCT clears Saraki Of False Asset Declaration Charges
Today, the Code of Conduct Tribunal (CCT) dismissed the charges of false asset declaration against Senate President, Bukola Saraki. Chairman of the tribunal, Danladi Umar, in his ruling said the prosecution team had failed to offer sufficient evidence to prove ...
Read More »Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè
Gbajúgbajà olórin ní ìlà oorùn adúláwò tí a mò si Diamond platnumz ti yanjú aáwò tí ó wà láàrin òhun àti ìyá omo rè léyìn wákàtí tí ó bá a wí fún àìso òtító . Ó pín eré oníse amóhùn ...
Read More »