Ìròyìn tó bá ọ̀pọ̀ lẹ́jafùú ni ìròyìn ‘Mo ti ní àrùn Coronavirus’ èyí tí Gómìnà Ṣèyí Mákindé gbé jáde ní ọjọ́ Ajé lójú òpó twitter rẹ̀. Níbáyìí tí ó ti lo ọjọ́ méjì ní ìgbélé lẹ́yìn ìkéde yìí, gómìnà ìpínlẹ̀ ...
Read More »Mo Ti Fi Ẹjọ́ Abani Lórúkọjẹ́ Tó Fẹ́ Fi Àwòrán Ìhòòhò Mi S’órí Ìtàkùn Àgbáyé Sun Ìjọba – Waka Queen
À fi kí Ọlọ́run gbani lọ́wọ́ ẹni tó ń ṣọ́ni tá ò ṣọ́ o, ló dífá fún kójú má ríbi,gbogbo ara lòògùn rẹ̀, bí gbajúgbajà olórin wákà, Salawa Abẹni ti sọ pé, òun ti fi ẹjọ́ abani lórúkọ je tó ...
Read More »Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirusÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Ni ipinle Eko ni ori ti ko ogun eniyan yo ni ile iwosan ti won ti n toju awon ti kokoro Covid-19 n ba ja. Bi o tile je pe ...
Read More »Adarí àgbà ilé ìwòsàn UCH kò ní àrùn Coronavirus mọ́
Họ́wùú! bí babaláwo bá ń kígbe ẹ̀fọ́rí, kín ni yóó jẹ́ àtubọtán aláìsàn? Kò jẹ́ jẹ́ bẹ́ẹ̀. Adarí àgbà ilé ìwòsàn ẹ̀kọ́ṣẹ́, UCH Íbàdàn Ọ̀jọ̀gbọ́n Abiodun Otegbayo ti yiijẹ o, kò ní àrùn Coronavirus mọ́ lẹ́yìn tó sàyẹ̀wò àrùn náà ...
Read More »Àwọn agbẹjọ́rò ta ko ìnáwó àti òfin kó-nílé-ó-gbélé Ààrẹ àti àwọn gómìnà
Orisiirisii awon agbejoro ati awon amofin pelu ojogbon lorisiirisii ni won ti n yo suti ete si igbese awon ijoba orileede yii, paapaa julo lori arun coronavirus to gbode. Won ni ko tile tona rara ki ijoba apapo dede kede ...
Read More »Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni ...
Read More »Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’Ekoo
Orí kó ènìyàn márùn-ún yọ lọ́wọ́ coronavirus l’EkooÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Alaisan marun-un ninu awon ti arun buruku covid-19 ti n ba finra lati bii ose meloo kan seyin gba idande. Yoruba bo “won ni alaare ko ki n ...
Read More »Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní Naijiria
Ènìyàn tó ní àrùn coronavirus wọ 131 ní NaijiriaÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Eniyan ogun lo tun kun awon ti arun coronavirus n ba ja ni orileede yii ni oni ogbon ojo, osu keta odun 2020.Metala ni Eko, merin ni ...
Read More »Ṣèyí Mákindé, gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìpàdé ètò ọrọ̀ aje Nàìjíríà l’òun ti kó àrùn COVID-19
Ṣèyí Mákindé, gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìpàdé ètò ọrọ̀ aje Nàìjíríà l’òun ti kó àrùn COVID-19
Read More »Crisis As Doctors, Nurses Pick Race After Suspected Coronavirus Cases Hit Lagos Hospital
The patients were brought in a private vehicle around midnight, with one of them coughing uncontrollably and showing other symptoms of coronavirus.
Read More »