Àwo̩n aronúpìwàda Boko Haram ké̩kò̩ó̩ parí
Ìjọba ṣetán láti ra irinṣẹ́, sanwó oṣù fún adúnkookò mọ́ni tẹ́lẹ̀ Àwọn ikọ̀ agbésùnmọ̀mí tó to mọkanlelẹgbẹta ti wọ́n jọ̀wọ́ ara wọn fún ìjọba, ti kẹ́kọ́ọ̀ jáde nílé ẹ̀kọ́ . Ìjọba sì ti setán láti má a san owó ìrànwọ́ ...
Read More »