Is there really such a thing as an unlimited data plan?
My airtel 3gb plan doesn’t last more than two weeks and I don’t download any file, please which network data plan lasts longer
Read More »Lolade Comments Off on Is there really such a thing as an unlimited data plan?
My airtel 3gb plan doesn’t last more than two weeks and I don’t download any file, please which network data plan lasts longer
Read More »ayangalu Comments Off on Akékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí Odò-ìwè (Swimming Pool) Ní Hòtéèlì.
Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).
Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Òrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan Ní Nàìjíríà Lo.
Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa pínpín ...
Read More »ayangalu Comments Off on Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa.
Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà. Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.
E jò ó Erànmílówó. Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó.
Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó. SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Shoygu reported to Vladimir Putin about successful liquidation of the head of ISIS
Source: https://cont.ws/@barbera/642188 Translated by Eugenia Today at the working meeting of the Russian Security Counsel the Defense Minister Sergey Shoygu reported to the Commander-in-Chief that the Russian Air Force in Syria liquidated more than 30 field commanders of the terrorist ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Syrian War Report – June 20, 2017: Situation Further Escalates In Syria
Voiceover by Harold Hoover The situation escalates in Syria following the US aviation attack against an Su-22 belonging to the country’s national air force. The Russian Defense Ministry said that the US move may be considered an “act of aggression,” ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Russian MoD declares it will shoot down any aircraft flying west of the Euphrates river
RT reports: The Russian Defense Ministry announced it is halting cooperation with its US counterparts in the framework of the Memorandum on the Prevention of Incidents and Ensuring Air Safety in Syria following the coalition’s downing of a Syrian warplane. ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more