Home / Jobs in Nigeria / Education / A list of carefully prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 4,900)

A list of carefully prepared Yoruba numbers (Onka ede Yoruba 1 – 4,900)

2,000 – Egbewa (i.e. Igba Mewa = 10 Two Hundreds)

2,100 – Orundinlegbokanla (i.e. Ogorun Din Egbokanla = 2,200 Minus 100)

2,200 – Egbokanla (i.e. Igba Mokanla = 11 Two Hundreds)

2,300 – Orundinlegbejila (i.e. Ogorun Din Egbejila = 2,400 Minus 100)

2,400 – Egbejila (i.e. Igba Mejila = 12 Two Hundreds)

2,500 – Orundinlegbetala (i.e. Ogorun Din Egbejila = 2,600Minus 100)

2,600 – Egbetala (i.e. Igba Metala = 13 Two Hundreds)

2,700 – Orundinlegberinla (i.e. Ogorun Din Egberinla = 2,800 Minus 100)

2,800 – Egberinla (i.e. Igba Merinla = 14 Two Hundreds)

2,900 – Orundinlegbedogun (i.e. Ogorun Din Egbeedogun = 3,000 Minus 100)

=============================================

3,000 – Egbeedogun (i.e. Igba Meedogun = 15 Two Hundreds)

3,100 – Orundinlegberindinlogun (i.e. Ogorun Din Egberindinlogun = 3,200 Minus 100)

3,200 – Egberindinlogun (i.e. Igba Merindinlogun = 16 Two Hundreds)

3,300 – Orundinlegbetadinlogun (i.e. Ogorun Din Egbetadinlogun = 3,400 Minus 100)

3,400 – Egbetadinlogun (i.e. Igba Metadinlogun = 17 Two Hundreds)

3,500 – Orundinlegbejidinlogun (i.e. Ogorun Din Egbejidinlogun = 3,600 Minus 100)

3,600 – Egbejidinlogun (i.e. Igba Mejidinlogun = 18 Two Hundreds)

3,700 – Orundinlegbokandinlogun (i.e. Ogorun Din Egbonkandinlogun = 3,800 Minus 100)

3,800 – Egbokandinlogun (i.e. Igba Mokandinlogun = 19 Two Hundreds)

3,900 – Orundinloko-ho (i.e. Ogorun Din Oko-ho = 4,000 Minus 100)

========================================

4,000 – Okohun / Okoho / Oko-hun / Oko-o (i.e. Ogorun Ati Ogorun Ogun = 100 and 100 Twenty Times)

4,100 – Orundinlegbokanlelogun (i.e. Ogorun Din Egbokanlelogun = 4,200 Minus 100)

4,200 – Egbokanlelogun (i.e. Igba Mokanlelogun = 21 Two Hundreds)

4,300 – Orundinlegbejilelogun (i.e. Ogorun Din Egbejilelogun = 4,400 Minus 100 )

4,400 – Egbejilelogun (i.e. Igba Mejilelogun = 22 Two Hundreds)

4,500 – Orundinlegbetalelogun (i.e. Ogorun Din Egbetalelogun = 4,600 Minus 100)

4,600 – Egbetalelogun (i.e. Igba Metalelogun = 23 Two Hundreds)

4,700 – Orundinlegberinlelogun (i.e. Ogorun Din Egberinlelogun = 4,800 Minus 100)

4,800 – Egberinlelogun (i.e. Igba Merinlelogun = 24 Two Hundreds)

4,900 – Orundinlegberinlelogun (i.e. Ogorun Din Egberinlelogun = 5,000 Minus 100)

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti