Home / Art / Àṣà Oòduà / Akékòó ilé -èkó Nwafor Orizu College Nsugbe ni àwon omo egbé òkùnkùn yin ìbon pa. 
nocen

Akékòó ilé -èkó Nwafor Orizu College Nsugbe ni àwon omo egbé òkùnkùn yin ìbon pa. 

  Léyìn àrídájú tó ji-n-gí-ri, mo le f’owó s’òyà pé pé ilé-èkó Nwafor Orizu College of Education Nsugbe ti pàdánù tí ó pò .
  Arákùnrin Mr Osaji Charles, tí ó jé Mr NASELS télè (2013/2014 session), ni won yín ìbon fún tí a kò sì mo eni tí ó yin ìbon náà níbi tí kò jìnà sí “ota  Queen “. Mr Don Charles, bí ó se dáhùn lórí èro ayélujàra (facebook), ó ye kí ó parí ìdánwò àsekágbá ti eka-èkó rè ní ojó etì ojó ketàlélógún osù keje odún tí a wà yí (21st of July) tí ó sì ye kí o se ayeye ìkékòó jáde ní ojó karùndínlógbòn (25th) nígbà tí ó ti parí gbogbo ohun míràn tí ó ye kí ó se.
A bá gbogbo ìdílé Osaji kédùn, pèlú àwon akékòó eka-èkó èdè gèésì English department NOCEN, pèlú gbogbo àwon ilé-èkó t’ókùn ní agbègbè náà. Àkókò yí ni inú wa bàjé púpò .
 Sùn -un re oooo

Continue after the page break for English Version

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

masoyinbo

#Masoyinbo Episode Seventy-three: Exciting Game Show Teaching Yoruba language and Culture