Home / Art / Àṣà Oòduà / Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi !

Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi !

ORIKI ORILE IREMOGUN:-Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.
question
Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni. Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa so lona oko.Ki lo mu ki won maa so lona oko?

 

Ganiyu Soliu

Send Money To Nigeria Free

About Lolade

x

Check Also

Eyin eniyan mi e ba mi dahun ibeere miyi:

Bawo ni awon yoruba se nki awon wonyi: (1)Agbede. (2) Ondiri (3) Babalawo (4)Akope Ati Alaboyun