Home / Tag Archives: ibeere

Tag Archives: ibeere

Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi !

ORIKI ORILE IREMOGUN:-Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro. Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni. Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon ...

Read More »

Eyin eniyan mi e ba mi dahun ibeere miyi:

Bawo ni awon yoruba se nki awon wonyi: (1)Agbede. (2) Ondiri (3) Babalawo (4)Akope Ati Alaboyun

Read More »

Ejoo inje oleeto latimalo (CONDOM) fun iyawole?

Ekaro ekuu ojumon ooo. E bami  dahun ibeere yi ! Ejoo inje oleeto latimalo (CONDOM)fun iyawole?

Read More »

Haa Eyi tun ga ooo, to baje iwo ni kini wa se ?

Oko ka iyawo Ile e pelu Alee mo ori Ibusin won, to baje iwo ni oko yen kini wa se ?    

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb