Home / Art / Àṣà Oòduà / Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.

Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.

Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe eléyìí ni àbí Egúngún?. Eléyìí kojá òyé ti èmi.
Kí á ti è má fa òrò gún kò kúkú sí ìyàtò láàrin àwon méjèjì, èkú oko ni ìyàwó rè n wò kiri.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...