Máfi le ènìyàn lọ́wọ́
Ènìyàn ò da
Wọ́n lè sọ́ sómi
Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ
TÍ OSU TITUN BÁ DÉ, ARÁYÉ MÁA Ń YỌ̀ MỌ́ NI, WỌN MÁA BÁ GBOGBO WA YỌ AYỌ̀ IRE NÍNÚ OSU TITUN YÍÌ, PẸ̀LÚ ÀṢẸ ELÉDÙMARÈ . 1. Ọbàtálá/Òrìṣà-ńlá, Ọbalúayé/Ṣàpọ̀nná, Ògìrìyàn, Egúngún, Ìyàmi Àjẹ́. 2. Ifá, Ọ̀rúnmìlà, Èṣù-Ọ̀dàrà, Orí, Odù, Ọ̀ṣun, Ajé-Olókun, Ọ̀sányìn, Kórì, Ẹgbẹ́. 3. Ògún, Ìja, Ọ̀ṣọ́ọ̀sì, Erinlẹ̀, Òrìṣà Oko. 4. Jàkùta/Ṣàngó, Ọya, Aganjú, Yemọja, Ìbejì, Nàná-Bùkúù. 5. Ọbàtálá/Òrìṣà-ńlá, Ọbalúayé/Ṣàpọ̀nná, Ògìrìyàn, Egúngún, Ìyàmi Àjẹ́. 6. Ifá, Ọ̀rúnmìlà, Èṣù-Ọ̀dàrà, Orí, Odù, Ọ̀ṣun, Ajé-Olókun, Ọ̀sányìn, Kórì, Ẹgbẹ́. 7. Ògún, Ìja, ...
Ase