Gbajúgbajà amòfin oloyè Mike Ozekhome, SAN se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún ni ilé-ìtura Sharaton tí ó wà ní ìlú Abuja nínú àwon tó lo ni Ààre télè Goodluck Jonathan, ìyàwó rè Patience, igbákejì Ààre ilé ìgbìmò asòfin Ike Ekweremadu àti àwon èèyàn míràn…
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

