Home / Art / Àṣà Oòduà / ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé òsèlú APC ni won ti kí Ààre orílè èdè yí tí a mò sí Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi.

ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé òsèlú APC ni won ti kí Ààre orílè èdè yí tí a mò sí Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi.

Ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé APC ni ó ti kí Ààre Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi. Bauchi tí ó jé òkan Lára àwon gbòógì tí ó máa n gba àlejò Buhari láti ìgbà tí ó ti di Ààre .

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti