Home / Art / Àṣà Oòduà / Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé
ogogo

Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé

Ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, Ogogo.. ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ eré bọ́lùú wáyé

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà Yoruba to tí ta gbòǹgbò káàkiri àgbáyé ni Alhaji Taiwo Hassan tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí Ogogo ọmọ kúlódò jẹ́. Nítorí náà kò ya ni lẹ́nu nígbà tí ètò lónírúurú gbode kan fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún tó ṣe. Lára àwọn ètò náà ni ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ láàrin ikọ̀ ogogo, (Ogogo All stars) àti ikọ̀ to jẹ́ ti olórí Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Eko, ( Obasa All stars).
àá áà àà éé èè ẹ́ ẹ́ẹ̀ù ùẹ̀ ùẹ̀ ẹ̀ẹ̀ íí ìì óó òò ọ́ọ́ ọ̀ọ̀ ọọ úú ùù àà
Nígbà tí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà yóó fi parí ní pápá ìṣeré Agége, góòlù méjì làwọn ikọ̀ Obasa All Stars fi gbẹyẹ mọ́ ikọ̀ Ogogo lọ́wọ́ o.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Odùduwà

Ede Odùduwà: YORUBA – A Language of NIGERIA (and the WORLD)