Home / Art / Àṣà Oòduà / Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.
davido

Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.

Àwon olólùfé gbajúgbajà olórin tí a mò sí Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.
Davido le jé eni tí àwon ènìyàn féràn sùgbón ìyan kò so pé ó kojá ìbáwí, tí ó bá ye kí á ba wí…

Gbajúgbajà olórin, pín àwòrán ara rè tí kò wo aso sí orí èro ayélujàra (instagram) lésèkesè ni àwon èèyàn ti ń bu tí won sì gbà á ní ìmòràn látàrí rírí àbùkùn kan tàbí méji nípa àwòrán náà.

Nígbà tí inú àwon kan kò dùn sí àwòrán tí ó yà s’ára àwon míràn gbà á ní ìmòràn kí ó lo fá irun abíyá rè tí ó ti kún

Continue after the page break for English Version

About Lolade

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete