Home / Art / Àṣà Oòduà / Òsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.

Òsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.

Gbajúgbajà Òsèré Yvonne Jegede Fawole àti oko rè dun nú nígbà tí won bí omo tuntun tí ó tún jé Àkóbí won. Bí ó ti lè jé wípé a kò tí mò bóyà ako ni àbí abo sùgbón a mò wípé ó ti bímo.
Yvonne tí ó se ìgbéyàwó ní osú Èrèlé (February) odún tó lo, ti bímo láìpé.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti