Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won. Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ti iya naa fe so. O si seleri lati se atunse gbogbo ohun ti won on beere lowo ijoba.
E ma je n paro tan yin, mo ti yo ife Foyose bajebaje
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more




