Home / Art / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja
fayose

E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja


Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won.  Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ti iya naa fe so. O si seleri lati se atunse gbogbo ohun ti won on beere lowo ijoba.
E ma je n paro tan yin, mo ti yo ife Foyose bajebaje


Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event

Live Event Video: The Coronation of The 21st Olu of Warri

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event