Olórin, tí ó tún jé òtòkùlú ti n se isé takuntakun láti ri dájú wípé, sínétò Ademola Adeleke di Gómìnà ìpínlè Òsun ní ibi ìdìbò tí ó n bò ní ojó àbáméta yí. Ó tí è ti n sisé takuntakun ...
Read More »Akékòó tí ó se dáradára jùlo ní ilé-èkó gíga tí a mò sí ABUAD gba èbùn nlá fúm oríre yí.
Bí omo eni bá dára kí á wí, Akékòó gboyè ti ìmò tí ó n se ìtòjú ènìyàn tí a mò sí Medical Student, ti gba èbùn pàtàkí tí a mò dí Okò bògìnì àti owó goboi. Esther Azom ni ...
Read More »Gbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti
Gbajúgbajà a gbé òrò sórí aféfé ti gbe sí orí èro ayélujára tí a mò sí insitagiramu, láti jé kí gbogbo àgbáyé mò wípé òun ti bímo, nígbà tí ô ya àwòrán n’ílé ìwòsàn, tí ó sì pe omo máà ...
Read More »Iba Gani Adams pàdánù baba rè .
Baba Ààre Ona-kakanfo ti ilè Yorùbá tí a mò sí Iba Gani Adams ti lo. Pa Lamidi Adams tí ó ta téru nípà ní ojó Àbáméta ní ilé ìwòsàn aládáni ní ìpínlè Eko, baba kú ní ìgbà tí won fé ...
Read More »Asòfin egbé APC, tí a mò sí Hon. Timothy Owoeye, fi èjè wè ní òrú gànjó.
Owó pálábá Asòfin egbé APC tí ó sì jé gbòógì , tí ó sì jé asojú ilé ìgbìmò asòfin tí Ilésà ní ìpínlè Osun, ni owó bá nígbà tí ó n fi èjè wè ní àrin òru tí ó sì ...
Read More »Arákùnrin Oyinbo yí ló fé ìyàwó rè tí ó jé omo Edo, tí won sì se ìgbéyàwó ìbílè Alárédè.
Òyìnbó kò mà le mú ojú kúrò lórò lára àwon omoge orílè èdè Nìjíríà rárá, nítorí won mò wípé arewà ni won, won sì mo ìké oko se, bí kò bá jé béè ogún-l’ógbòn àwon òyìnbó ni ó ti fé ...
Read More »Chimamanda Adichie se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún mókànlélógójì (41) lóòní.
Chimamanda Ngozi Adichie ni won bí ní ojó keèdógún osù kesàn-án odún 1977 (15/09/1977), jé olùkòwé ní orílè èdè Nìjíríà, ó n ko ìtàn kékeré àti èyí tí ó pò, ó n ko èyí tí ó jé ìtàn ojú gbangban ...
Read More »Owolabi Awodotun Aworeni omo Àràbà télè, Araba Adisa Aworeni, di Àràbà Àgbáyé.
Gbogbo onísèsi àgbáyé ti darapò láti fi Omo Ekùn je Àràbà káàkiri àgbáyé. Lóòótó òpò ni yóò ma rò wípé báwo ni ó se tún jé wípé omo Àràbà tí ó sísè náà ni ó tún jé, súgbón eni orí ...
Read More »Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán
Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán . Gbajúgbajà Bbnaija tí a mò sí Miracle tí ó lo fún ìsinmi olójó gbooro ti padà sí orílè èdè Nìjíríà gégé bí ó se kakè sí ...
Read More »Reekado Banks gba Larry Ekundayo l’álejò ní ilé rè.
Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára. E wo àwòrán won ní ìsàlè.
Read More »