Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ...
Read More »Àwòrán olópàá tí ó n só Afárá Apogbon (Apogbon Bridge).
Wón ti so síwájú télè wípé àwon olópàá Nàíjíríà n sisé takuntakun láti só agbègbè Apogbon bridge tí a mò fún àwon dánàdánà.
Read More »Omodé yìí mà ní opolo oo.
Omokùnrin odún méwàá (10yrs) yí láti ìpínlè Anambrah ní orílè èdè Nàíjíríà , òun ni ó kó ilé yí orúko rè ni Chinecherewu. Mi ò le fun ní owó lásán ” ó n’ílò kí gbogbo ayé rí èyí.
Read More »Ódára kí èèyàn San ìdàméwàá, D’banj ni ó so béè .
D’banj pín èróngbà rè nípa ìdàméwàá. E jè rí, àwon omo Nàíjíríà ti da l’óhùn bí ó ti yé.
Read More »Cristiano Ronaldo àti Georgina Rodriguez kí omobìnrin káàbò, Alana Martina .
Cristiano Ronaldo ti kí omo rè kerin káàbò, Alana Martina ni orúko rè. E kú oríre Ooo.
Read More »Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón ó ti di olóògbé.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook)se so, odókùnrin yí ye kí ó se ìgbéyàwó ni osù kejìlá sùgbón ó ti di olóògbé. Ó kú nínú ìjàmbá pèlú àwon tí ó kùn rè. Kí olórun te sí aféfé rere. ...
Read More »Wizkid ni ó gbé igbá orókè gégé bi okùnrin àkókó ní bi àmì èye AFRIMA ti odún yí ó sì pa Davido láyò.
Wizkid pa Davido, Techno àti àwon míràn tí ó wá fún àmì èye AFRIMA ti odún yí láyò. Wizkid gba èbùn fún orin rè ” Come closer ” tí ó ko pèlú Drake.
Read More »Jackie Appiah dàbí egbin nínú aso ìbílè tí ó wò.
Òsèré orílè èdè Ghana, Jackie Appiah, èyí rewà ju kí èèyàn fi ojú paáré lo, òsèré yí ló pin sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí níbi tíó ti wo aso ìbílè tí a mò ...
Read More »Ebube Nwagbo fi enu ko eja nlá tí ó n jé Dolphin ní Dubai fún ìsinmi.
Òsèré Ebube Nwagbo tí ó wà ní ìsinmi lówólówó ní Dubai ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram) àwòrán aso ìwè rè pèlú bí ó se n wè l’ódò àti eja nlá tí ó n jé Dolphin .
Read More »Ìmúra Nana Akua Addo fún AFRIMA ti odún yí.
Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.
Read More »