Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 70)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

World Ikin

#‎OkeItase2016‬! Preparation of the World Ikin

Ikin ifa agbaye/world ifa sacred palm but…we dem boys getting it ready for the festival… Yay??? See more photos after the page break

Read More »
tatakuku

E fu’n Foto yii ni Oruko

E daku’n e be wa fu’n foto yii ni Oruko ka’n to dara!

Read More »
asa yoruba

A ku ojumo oooooooo!

Oba to silekun ojo oni, yoo sina ayo fun wa, yoo sina aje fun wa, A ko no seru egbe wa, ire ayo wa ko ni fo wa ru(Ase). ‪#‎AKARA_IMORAN‬ : Ma se gbo oro okere, gbiyanju lati wadi ohun ...

Read More »

Gbiyanju lati toju obi i re !

Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je fun gbogbo wa lase Edumare(Ase). ‪# AKARA IMORAN‬ : Gbiyanju lati toju obi i re, niwon igba ti obi ...

Read More »
Orunmila

Llegando a oke igeti home de Orunmila.

Foto kerediti –

Read More »
court

Idajo mi ree…

Leyin gbogbo atotonu awon agbejoro mejeji ati iwadi to peye, ariipe ojebi esun ti a fikan e, nitori na idajo mi ree, ile ejo yi so e sinu: i) igbega; ii) aseyori; iii) idunnu; iv) ayo; v) ire owo; vi) ...

Read More »
ogun

Ogun our Generalissimo

Ase! Ogun Lakaaye, Onija oole Asegbe l’eyin eni to wuu Koriko odo tii ru minijo. A casa de Ogun não têm portas. Portanto, independente dos problemas que tenhamos em nossa vida sempre podemos buscar auxílio e também a resolução dos ...

Read More »
yoruba

Idile Alayo Toni

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...

Read More »
asa yoruba

Ogulutu Oro Toni

Hummmmmm mase beru ‪#‎eniyan‬ ju ‪#‎Eledumare lo… ‪woo orewa‬ Kosi nkan tenikan o fi enikan Se,gbiyanjuy latile koju ota re loni,jeki o mo wipe Akinkanju eyan nio ‪#‎nje‬ O mo wipe toba ti nberu eyan ju yio pada sorare di Olodumare niwaju ...

Read More »

Eeto Owe L’esin Oro 4

Mo ki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro. Laakoko, mo dupe lowo Olodumare ti o funwa ni oore-ofe lati tun pade loni, leyin igba ti a dagbere fun eeto ni ose to koja. Moki kabiyesi ...

Read More »