.( Ni gbongan adulawo ni Yunifasiti Afonja, awon eniyan n wole leni tere, eji tere. Won n gba tikeeti, won si n wole jokoo. Awon ti o fe safihan sinima naa n gunke, won nso. Won nfa waya, won gbaradi. ...
Read More »Iwure Owuro – 14.03.2016
*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni ...
Read More »Iwa Dabi Eyin
Toju iwa re iwo ore mi. Maa ranti wipe iwa-lewa. Ewa bii iwa ko si. Bi o ba dara bii egbin. Ti o tun rewa bi okin. Eran ikan ni lojo tiku ba de. Sugbon iwa lohun ti kii ku. ...
Read More »Owe Toni: Pari owe yi
1.Awolu mate e????? 2.Enitio dasofun ni??????
Read More »GBEJÉÉ KIO NIYI
Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké, ...
Read More »ibere ranpe daruko awon nkan meji yi ati wipe awon wo ni won nlo ?
jowo fi idahun re sowo si mi ti o ba je ojulowo omo yoruba
Read More »Iya Ni Wura Iyebiye – Anita iPraise Ikotun
Lyrics (Yoruba) Iya ni Wura iye bi ye Ti a ko le f’owo ra O l’oyun mi f’osu mesan O pon mi f’odun meta Iya ni wura iye bi ye Ti a ko le f’owo ra Lyrics ( English) ...
Read More »Biodun Okeowo lori eto Gbajumo Osere
Ara lori eto Gbajumo Osere
Nje toba jepe Eyin Ni arakunrin yi
Kilerope Elese Fun Iru nusi bayi ?
Read More »