Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.
Read More »Tiwa Savage gbégbà orókè níbi àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi Alade lówó .
Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí. Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey ...
Read More »Isé abe tí ó bùáyà, Hushpuppi káàbámò lábé abe , ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Léyìn isé abe ; Hushpuppi káàbámò, ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Read More »Ejò sèbé tí mo won pa ní Ofoni Sagbama ní ìpínlè Bayelsa .
Sèbé nlá ni won pa ní agbègbè Ofoni ní ìjoba ìbílè Sagbama ní ìpínlè Bayelsa . E wo bí won se ge fún obè aláta yéríyérí.
Read More »D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin Dino Melaye .
D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin ni ó pín àwòrán yí “koko master náà ni”.
Read More »Won gbìmò láti da ilé mi wó, Dino Melaye se béè fún Yahaya Bello.
Asojú ilé ìgbìmò asòfin Melaye ti tako Gómìnà ìpínlè Kogi Yahaya Bello tí ó gbèrò láti wó ilé rè ní ìpínlè Kogi. E kàá dáadáa.
Read More »E wo bí olùyà yí se ya àwòrán Teckno.
Bí mo se ri ní orí èro ayélujára (Instagram), mi ò ti è mo ohun tí mo fé so, sé Techno sì ma san owó èyí bí.
Read More »Yomi Fabiyi ni Eniola Omoshalewa Eunice fi èsùn ìbálòpò kàn.
Ogún-l’ógbòn àwon eléré orí ìtàgé ni ó n fi tipátipá béèrè ìbálòpò lówó àwon èèyàn láti le jékí won hàn nínú eré ti orílè èdè Nàíjíríà (Nollywood) gégé bí ìyá kan àti eni tí ìsèlè yí selè sí se ...
Read More »Àwòrán tí ó ti pé ti Fela Kuti àti Femi Falana, agbejórò rè .
Àwòrán ògbó-n-ta-rì-gì olórin ní orílè èdè Nàíjíríà, Fela Anikulapo kuti àti agbejórò rè. Gbajúgbajà agbejórò tí ó tún jé bàbá ìlúmòóká olórin Falz d bahdguy ògbéni Femi Falana àti bàbá Beko Ransom Kuti . Mo gbàgbó wípé òrò ilé-ejó ni ...
Read More »Skolopad wo aso tí ó fi sósèjì se lo sí ibi láti gba àmì èye South African Feather.
Àwòrán tí ó gba èro ayélujára kan ti àmì èye south African Feather ti odún yi ni ìmúra àwon èèyàn kò bójúmu rárá. Olórin kan ní South African “Skolopad” wo aso tí ó kún fún sósèjì àti àpò èédú ...
Read More »