It just means that you have others around you that do not share the same emotions. Loneliness can be felt even if you have people around you. It is the emotional loneliness that makes you sad. But now you have ...
Read More »Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!
OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa
Read More »Foto ode’oni – 13.07.2016
Saheed osupa akorede ati baba wande.
Read More »Ejowo eni to ba mo olorin yi ko ko oruko re
Edakun kini oruko olorin yii
Read More »Lakinni Ajakinni Ajinni…
Lakinni Ajakinni Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Alara, Alara pe o loruko, odi eni ajiki. Lakinni Ajakinni Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Ajero, Ajero pe o loruko, odi ...
Read More »Gbogbo wa ni o bo ikin la! Aase!
IFA NI Asese roko agbe adabi akiti ohun obo Adifafun Ajala yobo Ikin la lese oke ebo won ni kose ogbebo ni be osebo bi kasai bokinla olowo Ajala bi kasai bo Ikinla emin ateyin ololufemi gbogbo wa labo ikin ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 09.07.2016
Hummmmmmmm igbiyanju lagbe ngba Olohun lomu isu ta #woo_orewa Nje o mo pe eni tio sun(sleep) lo nsun(move)????? ??? Gbiyanju lati tesiwaju loni majeki ijakule re fao seyin nigbesi aiye re #gbomi_dada Koseni tio ni #sugbon tie gboju re kuro ...
Read More »Akara Imora’n toni – 09.07.2016
*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. #AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...
Read More »Gbogbo Ile e ma binu simi ooo
Oro buruku pelerin erin’kkkkkk Mo sese ri eran ewure ni ibi to pokunso so ni in Eran ti moni ki a fe se odun lo pokunso yi ooo Mi o mon nkan to nba leru o erin’kkkkkk
Read More »IYA wa Bukky Ajayi sun re oooooo
Bi oro aye se ri ni yen oooo Bi poopo sin-sin odun se wa nta. Olodumare ti se bi o se nse fun awon ebi iya wa Bukky Ajayi Iya ti lo ni aro yi o. Gbogbo eyin Omo Ooduarere o ...
Read More »