Is it not amazing that they actually want me to believe that the Yoruba culture comes from Egypt? Or that Ifa originates from China? Or that Orunmila is from Libya or some other exotic country? I always tell them: what ...
Read More »
admin Comments Off on Yoruba culture originates from Egypt?
Is it not amazing that they actually want me to believe that the Yoruba culture comes from Egypt? Or that Ifa originates from China? Or that Orunmila is from Libya or some other exotic country? I always tell them: what ...
Read More »Lolade Comments Off on YORUBA: Oro iyanju fun awon Oba ile Yoruba.
YORUBA: Oro iyanju fun awon oba ile Yoruba. English: A word of advice for all Yoruba kings. “Oun ti a ba pe ni Ori, a kii fi te ile.” meaning whatever we call head, one does not tread the floor ...
Read More »admin Comments Off on Ohun to pada sele si maanu to lo gbadun ara re nile asewo buru jai
Maanu yii lo lo gbadun ara re nile asewo kan niluu Benin. Aisanwo leyin igbadun lo di ohun ti won da igbati jo fun un.
Read More »admin Comments Off on Senato ipinle Ekiti pin iresi fun awon eniyan bi Fayos
Awon eniyan ti won gbe ni agbegbe ekun Guusu Ekiti gbajo tilu tifon nigba ti arabirin Biodun Olujimi ti n soju won nile igbimo asofin agba Abuja si obitibiti ounje wolu l’Ojobo ose to koja yii. Apo iresi, ororo ati ...
Read More »admin Comments Off on “Awon irinse ti a n lo ti darugbo”- Oga panapana ilu Eko
Oga agba ileese panapana ti ijoba apapo, Federal Fire Service, eka ti ipinle Eko, Ogbeni Aderemi Olusola Theophilus ti sapejuwe ikiyesara gege bi ogun-ajisa lati dena ijamba ina abaadi. Ninu oro re, eleyii to so lori telifisan ipinle Eko, o ...
Read More »admin Comments Off on Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo
Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere ...
Read More »admin Comments Off on Obirin kan bi omo sinu Keke Maruwa
Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun. Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo ...
Read More »admin Comments Off on Won ti fi Ladoja je Osi Olubadan
Won ti fi Senator Rashidi Adewolu Ladoja je Osi Olubadan lonii (01/01/16) ni aafin Oba Samuel Odulana Odugade, Olubadan tile Ibadan.
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more