Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi Ṣé wọ́n ní kìí jẹ́ ti baba t’ọmọ, kó mọ́ ní ààlà. Èyí ló díá fún bí àwọn ẹbí olóògbé Abíọ́lá Ajímọ̀bi tí sàlàyé pé ,kí àwọn olùkẹ́dùn, ó má wulẹ̀ ...
Read More » 
		ayangalu Comments Off on Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi
Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi Ṣé wọ́n ní kìí jẹ́ ti baba t’ọmọ, kó mọ́ ní ààlà. Èyí ló díá fún bí àwọn ẹbí olóògbé Abíọ́lá Ajímọ̀bi tí sàlàyé pé ,kí àwọn olùkẹ́dùn, ó má wulẹ̀ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Abiola Ajimobi sùn un re
Ikú pàgbẹ̀ àṣírí aláró tú.Ikú pàlùkò àbùkù kará ìkosùn.Ọrùn má kánjú, gbogbo wa la dágbádá ikú.Ìgbà átàsìkò ẹ̀dá ló só kùnkùn.Gíńgín ladáhunṣe tó mewé e re.Gbogbo wa lòpè nípa àkúnlẹ̀yàn.Òkú ń sunkú òkú, akáṣọlérí ń sunkú ara a wọn.Sùn un ...
Read More »ayangalu Comments Off on Colourful Photos: The Olowo of Owo Kingdom
His Imperial Majesty, Alaiyeluwa Oba Ajibade Gbadegesin Ogunoye III, The Olowo of Owo and Paramount Ruler of Owo KingdomPicture: Igogo festival 2019 See more photos bellow
Read More »Aku ataro óò Adé kú ọjọ yìí Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin náà?????? #iya lájé
Read More »ayangalu Comments Off on Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn
Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn Ṣé ọlọ́tọ̀ ní t’óun ọ̀tọ̀, a díá fún òkú tó kú ńlé, tí wọ́n sin s’óko.Àgbà Imọlẹ̀ kan nlẹ yìí ti fèsì sí ìṣẹ̀lẹ̀ ààrá tó sán láìpẹ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom
L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tí ì tán, èèyàn ńlá kò níí sinmi àròyé.Sinimọ́ oríta sì ń tẹ̀síwájú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odún dé, Gbogbo Irúnmolè e gbé ire wá
Our World Ifa festival has come, all divinities, we request that goodness is brought to us all. Just listen to Òsé Orógbe as follows:- Eésan ò sé gbá lójúÀkeèkèé ò se é dìníbòAdífá fún Odún tíí se Yèyé ObaÒsé tééré ...
Read More »ayangalu Comments Off on O̩ló̩run sì máa gbè̩san ikú bàbá mi – O̩mo̩ o̩ko̩ olóyún
Olorun si maa gbesan iku baba mi – Omo ojo OloyunOjo ketalelogun osu kin-in-ni odun yii ni awon adiha-Moran kan lo yinbon pa Alhaji Fatai Yusuf ti gbogbo eniyan mo si oko oloyun. Lati igba naa ni awon olopaa ti ...
Read More »Ebo is powerfulEbo is prayerEbo solves the unseen problemsEbo helps prevent tribulationsEbo cleanse my soulIt makes me feel completeEbo doesn’t require human partEbo is pureEbo is the key I have used Àkùko to offer Ebo for victoryI have used Etù ...
Read More »ayangalu Comments Off on Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19
Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to ...
Read More » Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more