Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ ...
Read More »#Òmìnira
Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ...
Read More »Ogboni – Isese Lagba
EEPA MOLE !!!
Read More »ARUGBA is no longer a Virgin maid
Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people ...
Read More »Isese la wa nbo n’Ife ka to rire(Ogunderin)
It is Ancient Religion we worship in Ife, the cradle of Yoruba Religion, before we receive goodness . It started in 1987 when some enlightened people such as Oloye Sola Atanda, Asiwaju Awo Agbaye Ile Ife, Late Wale Egberongbe, Dr. ...
Read More »Tale Feran Ju Ninu K1 Ati Ksa
Ogulutu Oro Toni 18.08.2016
Hummmmmm ohun ta nfe la ndaso bo koseni tio mope irun ori poju irun ibikan lo woo orewa Nje o mope ohun taba gbe pamo ni I niyi? Moraso ogun mofi han eyan ogbon hummmmmm. gbomi dada Bisu eni bata ...
Read More »Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!
A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Oruko kan fu foto yi ?
Oruko kan fu awon arakurin yii ?
Read More »Aja To Rele Ekun To Bo..
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »