Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ rẹ̀ ní dúníyàn. Àsamọ̀ ...
Read More »Abiola Ajimobi sùn un re
Ikú pàgbẹ̀ àṣírí aláró tú.Ikú pàlùkò àbùkù kará ìkosùn.Ọrùn má kánjú, gbogbo wa la dágbádá ikú.Ìgbà átàsìkò ẹ̀dá ló só kùnkùn.Gíńgín ladáhunṣe tó mewé e re.Gbogbo wa lòpè nípa àkúnlẹ̀yàn.Òkú ń sunkú òkú, akáṣọlérí ń sunkú ara a wọn.Sùn un ...
Read More »Abọ ìwádìí yóó ṣọ pàtó ikú tó pàwọn òṣìṣẹ́ wa– Àjọ FRSC
Abọ ìwádìí yóó ṣọ pàtó ikú tó pàwọn òṣìṣẹ́ wa– Àjọ FRSC Ìlú u gángan lọ̀pọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ láyé,n Iàwọn àgbà se ṣọ pé,ẹ̀yìn ló kọ sẹ́nìkan, n tó kọjú sẹ́lòmíìn.Bí a kò bá gbàgbé, àìpẹ́ yìí ni ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà pàtì ...
Read More »INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo
INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo Ṣé àwọn àgbà ní bí eégún kò bá ṣe n tó tóbi, atọ́kùn rẹ̀ kìí tú ìdí rẹ̀ wò. Àjọ olómìnira tó ń ṣe kòkárí ètò ìdíbò Orílẹ̀ yìí tí fọnmú ...
Read More »Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò– Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti ilú Àbújá ti yẹ àga mọ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Adams Oshiomhole nídìí Ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mẹ́tà ti adájọ́ Eunice Onyemanam sójú fún ni wọ́n fẹnu ...
Read More »Orisirisi: Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC
Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC Àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà EFCC sọ pé àṣírí àwọn ayédèrú òṣìṣẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àjọ tó ń ṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nípìńlẹ̀ Kwara ti tú sí àwọn ...
Read More »Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì
Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì Ẹgbẹ̀ta lé lọ́gbọ̀n o dín mẹta èèyàn (627 )tuntun míì ló ṣẹ̀sẹ̀ lùgbàdi àrùn Kofi -19 ní Nàìjíríà. Àjọ tó ń rí sí ìdènà àti amójútó àjàkálẹ̀ àrùn apinni ...
Read More »Olu Jacobs sì wà láàyè
Olu Jacobs sì wà láàyè Agba oje ninu ere ori itage ni ede Oyinbo, Alagba Olu Jacobs ni awon iroyin eleje kan n gbee kiri lori ero ayelujara lati aaro oni pe, “olodi baba naa ti lo je ipe awon ...
Read More »Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩
Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩ Lati odun to koja ni ijoba apapo ti yi ojo isejoba awa-ara-wa kuro ni ojo kokandinlogbon osu karun-un odun si ojo kejila osu kefa odun. Eyi waye lati fi ...
Read More »O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’Eko
O̩wó̩ pálábá 185 nínú o̩mo̩ e̩gbé̩ òkùnkùn ségí l’EkoYínká Àlàbí Komisona olopaa ni ipinle Eko, Ogbeni Hakeem Odumosu tenu moo ipinle Eko ko ni faaye gba egbe okunkun rara. Eyi lo faa to fi tete pakiti mole lati gbogun ti ...
Read More »