Ìmúra Nana Akua Addo fún AFRIMA ti odún yí.
Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìmúra Nana Akua Addo fún AFRIMA ti odún yí.
Òsèré orílè èdè Ghana , Nana Akua Addo ya ni lénu pèlú ìmúra rè lo sí AFRIMA odún yí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Tiwa Savage gbégbà orókè níbi àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi Alade lówó .
Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí. Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Syria War Report – November 13, 2017: ISIS Conducts Suicide Attempt To Seize Back Al-Bukamal
https://southfront.org/syria-war-report-november-13-2017-isis-conducts-suicide-attempt-to-seize-back-al-bukamal/ The battle for al-Bukamal heated up last weekend as ISIS terrorists conducted a successful counter-attack against the Syrian Arab Army (SAA) and Hezbollah in the border city. According to local sources, ISIS re-established control over a major part of ...
Read More »Lolade Comments Off on 2face celebrates wife, Annie Idibia as she clocks 33
2baba Idibia is celebrating his beautiful wife, and mother of 2 of his kids, Annie Idibia, as she turns a year older today. The singer, shared the below beautiful photo, and wished her the very best in life, while also ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Isé abe tí ó bùáyà, Hushpuppi káàbámò lábé abe , ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Léyìn isé abe ; Hushpuppi káàbámò, ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ejò sèbé tí mo won pa ní Ofoni Sagbama ní ìpínlè Bayelsa .
Sèbé nlá ni won pa ní agbègbè Ofoni ní ìjoba ìbílè Sagbama ní ìpínlè Bayelsa . E wo bí won se ge fún obè aláta yéríyérí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin Dino Melaye .
D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin ni ó pín àwòrán yí “koko master náà ni”.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Won gbìmò láti da ilé mi wó, Dino Melaye se béè fún Yahaya Bello.
Asojú ilé ìgbìmò asòfin Melaye ti tako Gómìnà ìpínlè Kogi Yahaya Bello tí ó gbèrò láti wó ilé rè ní ìpínlè Kogi. E kàá dáadáa.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on E wo bí olùyà yí se ya àwòrán Teckno.
Bí mo se ri ní orí èro ayélujára (Instagram), mi ò ti è mo ohun tí mo fé so, sé Techno sì ma san owó èyí bí.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Yomi Fabiyi ni Eniola Omoshalewa Eunice fi èsùn ìbálòpò kàn.
Ogún-l’ógbòn àwon eléré orí ìtàgé ni ó n fi tipátipá béèrè ìbálòpò lówó àwon èèyàn láti le jékí won hàn nínú eré ti orílè èdè Nàíjíríà (Nollywood) gégé bí ìyá kan àti eni tí ìsèlè yí selè sí se ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more