Orí ejò

Orí ejò

Bí kò bá sí ọpẹ́lọpẹ́ orí, à bá tí mú ejò digi lóko
Ìtàkùn mà lejò
Kíni yoo bá ejò ṣẹ́gun 
Orí ejò ní yoo bá ejò ṣẹ́gun 
Orí ejò

Mo sé ní ìwúre pe orí kálukú wa yoo báwa ṣẹ́gun ọ̀tá gbogbo
Akò ní di ẹran àmúso lọ́wọ́ ọ̀tá ooo

I pray for everyone of us that our head will safe us from any evil and any plans of enemy against us shall be in vain

Eu oro por todos nós que nossa cabeça nos protegerá de qualquer mal e quaisquer planos de inimigos contra nós serão em vão.

Awóyẹmí Ọlọ́run wà 1

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

EsuOdara

The Truth About Èṣù Òdàrà: Misjudged and Misunderstood.

Over the years, his name has been associated with evil and all manner of negativity. He is blamed whenever tragedy strikes; even those who consciously commit crimes often shift the blame onto him, saying “Isé Esu ni” (It’s Esu’s doing). It’s time to set the record straight. He is Onile Orita—the one who resides at the crossroads. Èṣù Òdàrà is the Òrìṣà of contemplation, which is why his abode is at junctions, and some of his sacrifices are symbolically placed ...