Home / Art

Art

Ilé Ọ̀rìsà!!!

Ilé Ọ̀rìsà!!!

That’s what an admire called the Òyẹ̀kú Méjì suite at the Àkòdì Òrìṣà. She used the Ile Ife dialect, Ilé Ọ̀rìsà. It is different from the Oyo dialect of Ilé Òrìṣà.  But it is absolutely appropriate that it is called ...

Read More »
1200 map of yoruba

#KnowYourOwnHistory: The Year 1200 map of the Yoruba cultural area of Nigeria and West Africa”

The Year 1200 map of the Yoruba cultural area of Nigeria and West Africa

Read More »
The map of the Yoruba cultural area of Nigeria and West Africa”

#KnowYourOwnHistory: The map of the Yoruba cultural area of Nigeria and West Africa”

‘Most people questioning the originality of Yoruba people who are domiciled outside southwestern Nigeria are ignorant, they can’t differentiate between ethnicity and geographical intercardinal locations. How can anyone doubt the originality of Yorubas in Nigeria while some are even domiciled ...

Read More »

Olójòǹgbòdu: The Wife of Death.

Sculpture at the Àkòdì Òrìṣà, Ile Ife, Nigeria

Read More »

Ó DỌWỌ́ ORÍ

Ó DỌWỌ́ ORÍ Gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá dọwọ́ Orí ẹ̀ láyé; Àlámọ̀rí ọmọ ẹ̀dá ènìyàn; Ó kúkú ń bẹ lọ́wọ́ Oríi wọn gbogbo. A díá fún PMB ẹni àyànmọ́. A bù fún PYO ẹni Orí ṣe lóore. Lọ́jọ́ tí wọn ó ...

Read More »

Ẹ̀FỌN

Ẹ̀FỌN Oníyánmú ń pa yánmú, oníyànmù ń pa yànmù, Ẹ̀fọn ń se yún-ùn yún-ùn L’étí ọmọ adáríhurun. Ẹ̀fọn kìí sùn bẹ́ẹ̀ni kòní jẹ́ k’ẹ́ni orun ń kùn ó sùn. Ẹ̀fọn ń gbọ́ pà Ẹ̀fọn ń gbọ́ pò Ìjùbàlà lọ́tùn-ún Ìjùbàlà ...

Read More »

Awon ti Ifa ba fi ran lo maa fi jise

Yoruba ronu….

Read More »

Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom

Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom. Bí ó tilè jé wípé won ti sún ìdìbò síwájú látàrí àwon ìsèlè àifójúrí kan tí àwon tí ó n se ètò ìdìbo se ...

Read More »

Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé.

Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé. Gbajúgbajà òsèré orí ìtàgé se àfihàn ewà rè nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà, tí ó sì ...

Read More »
esu is not satan walk 2018

When will this slander of our cherished heritage, “Esu” stop? #EsuIsNotSatan

Watching Nollywood Yoruba movies sometimes can be annoying.Most common utterances I regard very insulting are stated as follows:- Ti Esu ba fun o ni adie yoo gba malu lowo re If Esu gives you a fowl, he will demand a ...

Read More »