Home / Tag Archives: ifa

Tag Archives: ifa

ifa

Edi Alálà !!!

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? aku ijosin ifa toni to je ojo abameta, Olodumare ninu aanu re koni da emin wa legbodo lati le se pupo ijosin naa loke erupe o Ase. Idanileko ti aaro yi jade lati inu ...

Read More »

Ẹ̀rìndínlógún !

Ẹ̀rìndínlógún Èjì Ogbè Ogúnlénírinwó okọ́ Ọ̀tàlélégbèṛin àdá Wọ́n dárí jọ Wọ́n ń lọ bókè jagun Òkè kò jẹ Òkè kò mu Òkè ni yíò ṣẹ́tẹ̀ gbogbo ajogun. Twenty and four hundred hoes Sixty and eighty hundred machetes They conspired And ...

Read More »