Wasiu Alabi Pasuma, Oganla Fuji 1, pe eni odun mejidinlaadota (48) lonii. Ayeye ojo-ibi IbaWasila waye ninu ile re to kale si Omole niluu Eko nibi ti awon eniyan Olorun, ore ati ojulumo ti pejo lati ba yo ayo ojo ibi re naa. Igba odun, odun kan ni fun Orobokibo Creator. #HBDOganla
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more






