Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ijamba lorisiirisii. Gege bi alaye to te Olayemi Oniroyin lowo, apa ariwa ilu UK ni ijamba naa ti wopo julo nibi ti won ti ro gbogbo olugbe agbegbe naa lati sa asala fun emi won bayii.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more






































