Home / News From Nigeria / Breaking News / Mi ò ní dá DMs lóhùn mó – Davido so béè léyìn ìgbà tí ìkan nínú àwon olólùfé rè pa iró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò.

Mi ò ní dá DMs lóhùn mó – Davido so béè léyìn ìgbà tí ìkan nínú àwon olólùfé rè pa iró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò.

Ògá àkójopò HKN, Davido, tí ó pe ìkan lára àwon olólùfé rè obìnrin jáde, Sheilah Parker, tí ó gbe lo sí orí èro ayélujàra (snapchat ) láti p’aró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò pèlú arabìnrin náà. Olórin tí ó bèèrè wípé “Kílódé tí àwon ènìyàn fi rí báyìí? Ó tún jé kí won mò wípé òun kò ní dá àwon DMs lóhùn mó.
Àwòrán nìyí n’ísàlè….

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

“Ìyálóde, Eléékò & The Heavenly Companions: Discover the Mysterious Classes of Egbe in Yoruba Tradition”

Classes of Egbe (Heavenly Mate of Every Human) Also known as Alaragbo in some areas of Yoruba land, Egbe is generally more associated with children than with adults according to Eji-Ogbe. Based on the character traits of human on Earth, the Yoruba have classified Egbe into different categories. Ìyálóde Ìyálóde is regarded as the leader of Egbe on Earth. Leadership quality is most evident characteristic of this class of Egbe. Going by the name, it may appear that only females ...