Home / Art / Àṣà Oòduà / Awakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni ìpínlè Edo.

Awakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni ìpínlè Edo.

Òdókùnrin kan ni ó se àgbákò ikú òjijì ní ojó mélòó séyìn ní ìlú Jatu ní ìpínlè Edo, nígbà tí ó n gbìyànjú láti fònà sí òdì kejì, arákùnrin yí ni okò tí o n sáré fó ní orí tí ó sì pa á lésèkesè.
Ìsèlè burúkú yí ni a gbó wípé ó n fa wàhálà ní agbègbè náà kí ó tó di wípé won gbé òkú náà kúrò lónà.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti