Home / Art / Àṣà Oòduà / Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.

Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.

Èyí bani ní inú jé púpò, arákùnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà yí ti kú pèlú àwon mókànlà míràn ní inú ìjàmbá okò tí ó selè ní Foggia ní ilè Italy.

Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé yí, orúko rè a máa jé Mr.Roman Mgbeke láti ìpínlè Ebonyi, tí ó lo sí ibi isé pèlú àwon mókànlá míràn tí kú sùgbón tí won sàgbákò ìjàmbá okò tí méjìlá sì kú nínú won .

Àwon ebí rè kò tí gbó ìsèlè yí, e jòwó e báwa pín àwòrán yí tí won yóò fi ri.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti