Home / Art / Àṣà Oòduà / Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19 – Tinubu
tinubu

Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19 – Tinubu

Asiwaju agba fun egbe oselu APC, Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu ni oun ko ni arun ajakale coronavirus bi gbogbo eniyan se n gbee poori enu. O ni awon kan ni oun ti wa ni igbele olojo merinla pelu Oluremi.

Awon kan tile ni oun ti ko aisan naa ni eyi ti o mu ki oun ati Oluremi se ayewo arun naa.
Asiwaju ni ko je dandan pe ti eni to ba wa ni egbe eniyan ba ni arun, eni naa gbodo nii.


O ni awuyewuye yii gbile nigba ti awon eniyan gbo iku olori eso oun, Lati Raheem ti o file saso bora leyin aisan ranpe.


Asiwaju ni Lati Raheem je eda kan ti ko ki n fi ara re sere rara, bi o se mo pe o te oun die ni o ti gba ile iwosan lo, o kan je wi pe aisan lo se wo ko si eni to ri ti olojo se.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

APC Convention: The Moment Tinubu Arrived At The Eagle Square (Video)