Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu, ogun re niyii to daju bi ada. E wa ewe eti erin ti a mo si aloe vera ati igbo mimu tutu (india hemp), awon nnkan mejeeji yii ni e o lo papo. Ti e ba ti se eleyii tan, e da sinu iparun ti e n lo. E maa fi pa irun yin lojoojumo.
Irun yin yoo dudu, yoo tun ridi mule, irun naa yoo si fe e gun de ibadi yin.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


