Home / News From Nigeria / Breaking News / Aku ójúmó Toni ?
ifa oodua

Aku ójúmó Toni ?

Asiku ose ifa osun egbe Ori Toni ?
Ifa ni ibo legbe ibo lawure adifa fun orunmila baba yio so akapo re di oba ebo lawo nikose inje enitoba fe laje komo setutu ibo legbe ibo lawure.enitoba fe laya komo setutu ibo legbe ibo legbe.enitoba feni omo komo setutu ibo legbe ibo lawure.enitoba feni ire gbogbo komo setutu ibo legbe ibo lawure.
Ifa yio sowa di eni nla lawujo lase edumare ?
Ifa we open wealth for everyone of them?
Ase ifa?
Iba esu?

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

lil kesh

Jíjẹ́ olókìkí ní ọmọdé jẹ́ ẹrù wúwo púpọ̀ – Lil Kesh

Mary Fágbohùn Gbajugbaja olorin Naijiria, Keshinro Ololade, ti gbogbo eniyan mọ si Lil Kesh, ti sọrọ nipa didi olokiki bi ọdọmọkunrin. Olorin ‘Young And Getting It’ ṣàlàyé pé ṣíṣe àṣeyọrí ní kékeré jẹ́ “eru wuwo.” Lil Kesh ṣe ifihan eyi lori eto Esther laipẹ yi, eyi ti o gbe jade lori YouTube ni ọjọ keji osu karun-un, Ọdun 2025. Ó sọ pé: “Bí mo ṣe tètè di olokiki da bii eru wuwo. Mo di olokiki ni omode. Omo ọdún mọ́kàndínlógún ...