Ẹ̀rìndínlógún
Èjì Ogbè
Ogúnlénírinwó okọ́
Ọ̀tàlélégbèṛin àdá
Wọ́n dárí jọ
Wọ́n ń lọ bókè jagun
Òkè kò jẹ
Òkè kò mu
Òkè ni yíò ṣẹ́tẹ̀ gbogbo ajogun.
Twenty and four hundred hoes
Sixty and eighty hundred machetes
They conspired
And launched a war against Oke, the Hill
Oke does not eat
Oke does not drink
Oke will defeat the plot of all malevolent forces
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

