Ojú.
Ojú lalákàn fi í sọ́rí.
Ojú oró ní í lékè omi.
Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí.
Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo.
Eyes–Oju
With the eyes, the crab watches the ori.
Oju oro stays atop standing waters
Oju will not disgrace us in Oju Ife
Oju will not depart from all of us siblings of Awo
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


