Home / Author Archives: admin (page 28)

Author Archives: admin

Dasuki Sambo

Sambo Dasuki wo gau! Falana setan lati gbe lo si ilejo idaran ti okeere

Agba ninu ise amofin to tun je agbejoro ti n ja fun eto omoniyan, Ogbeni Femi Falana ti seleri lati gbe oludamoran nipa eto abo fun ijoba apapo tele ri, Sambo Dasuki ati awon akegbe re ti won ka modi ...

Read More »
ori

Being older doesn’t guarantee leadership!

Atete d’aye o kan t’egbon Eni Ori san ni nje baba (Ogunda bede ) Translation Being older doesn’t guarantee leadership Only those endowed by Ori become father. Congratulations once again to His Imperial Majesty, Arole Oduduwa, Alayeluwa Oba Adeyeye Enitan ...

Read More »
ORISA incarnation

ORISA incarnation

“ORISA incarnation is the peak experience of divine consciousness of the spirit… Feeling and seeing what one believes spiritually can change every mythological stories of every fork-lores to become the grandest realistic fact of actuality…. Inter-relationship with the Spirits on ...

Read More »
yoruba language

Ijinle Ohun Ife: The Yoruba Language of The Gods

Oluporo Ikaomesi Ijenjeniwonran, D’Ifa fun Olodumare ti yio t’orun fimule mu ebora se….. Igare-Osule, gbogbo eriwo ni foribale fun alase ‘Ijinle Ohun Ife’………………… { ‘Oluporo Ikaomesi Ijenjeniwonran (Sealers Of Every Words & Languages), Divined for the Almighty God that initiated ...

Read More »
kettle drum

Obatala & His Kettle Drum !

Igbin Drums are the sacred Drums of Obatala The broken poison box The broken sword Ifa divination was performed for Mobikugbe Mother of hare (Ehoro) Oriṣaala, lover of song and drum Also an elder among all oriṣas He has a ...

Read More »
ifa odu

Post of the Day !

I never once in my life regrets ever since I started listen to voice of OLODUMARE through IFA. Is the only way to hear the true/real voice of OLODUMARE try and see.

Read More »
fayose

Akasu oro Fayose: “Eni ba fori so mi, yoo fo yangayanga”

Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose, ti fi da gbogbo ara ilu loju wi pe didun losan yoo so fun egbe alaburada, PDP, ninu eto idibo alaga ibile eleyii ti yoo waye lojo kokandinlogun osu kejila odun yii (19-12-15). Sugbon ...

Read More »
Taye Ogunlaja

Taye Ogunlaja: Won ti pa oloye omo egbe NURTW tiluu Eko

*Won gun un lobe lorun pa ni Awon olopaa olotelemuye, eka ti ile ise olopaa ti n risi iwa idaran to wa ni Panti, Yaba ti bere ise iwadii to gbepon bayii lati mo odaju eda to seku pa Taye ...

Read More »
ooni

Awon foto lati ibi iwuye Oba Adeyeye Enitan, Ooni ti Ile-Ife (Apa-Keji)

Oba Babatunde Enitan Adeyeye Ogunwusi Ojaja II

Read More »
Reverend Chukwuemeka Ezeugo

Ile ejo to gaju lo ni yoo pari idaju iku Reverend King

Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si Reverend King yoo ma waye. ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb