Home / Author Archives: admin (page 31)

Author Archives: admin

What Is Ifa

Today is another Ose Ifa.

We should follow the words of Ifa in Irosun meji cast. Ahere o ku iwo nikan ninu oko Eru o ba ‘ba niju O dijo ojo ba ro ka’here o to deleni ninu oko Adifa fun Egbe Ope Tii somo ...

Read More »
agba

Art of the Day: Àgbá

Artist: Undocumented Yoruba artist. Title: Àgbá Medium: wood, hide, pigments. Date: lost Agba’ just like edi-iwori speak:edi gbagbagba, iwo jegejege adifa fun agba to nlo re ka olomo

Read More »
ifa

Ifa: Check out top 72 Odus

There are 72 Odus that says a Devotee needs to be initiated to Ifa. The list: 1- OGBE WENA 2- OGBE ODI 3- OGBE ROSO 4- OGBE BARA 5- OGBE KANA 6- OGBE YONO (OGUNDA) 7- OGBE KA 8- OGBE ...

Read More »
ifa rule

AṢẸ: Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi..

Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi tin se owun gbogbo ti ikan ko lori (wọn ni ẹbọ nikose..orùbọ tan lowa di oni re gbogbo) Njẹ ori ẹni ni awure, eníyan bí ẹbáá ji lowurọ kí ẹdí ẹlẹ́da yin ...

Read More »

7 Ideal Types Of Men Women Can’t Never Resist

Maybe you have wondered why some guys have all of the luck as it pertains to women? It’s no secret that certain archetypal males have now been proven over and to be irresistible to women — and it’s not alone ...

Read More »

IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo

Ese ‘o gbero ni Ikenne Paradise ni mama wa bayi – Pst Adeboye Opelope Mama Kapenta nii nba je – Pst Bakare Okunrin to feran ibalopo pelu okunrin farahan ni Abeokuta Oju to maa ti awon ti won nbu ijoba ...

Read More »

Nje eleyii ni ona abayo fun awon obirin?

Read More »

Oga olopaa yari ooo

Kosi ohun teeyan ko ni ri tan ni Naija yii sa. lol

Read More »
Akintunde Ayeni

“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee

Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni  maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe,  Dokita Akintunde ti ...

Read More »
fayose

Fayose niso eleja

E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb