Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Mo lero wipe gbogbo wa la sun dokan daradara aku isimi opin ose, mosi fi asiko yi ki gbogbo àwon ore mi ti won je omo leyin kristi wípé eku odun eku iyedun emin ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ifa naa ki bayi wipe: Òkàn sá
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Mo lero wipe gbogbo wa la sun dokan daradara aku isimi opin ose, mosi fi asiko yi ki gbogbo àwon ore mi ti won je omo leyin kristi wípé eku odun eku iyedun emin ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Genevieve Nnaji ya àwòrán pèlú àwon agbófinró obìnrin méjì .
Genevieve Nnaji ya àwòrán pèlú àwon agbófinró obìnrin méjì . Gbajúgbajà òsèré, Genevieve Nnaji tí ó dàbí egbin nígbà tí ó ya àwòrán pèlú àwon agbófinró obìnrin méjì yí . Òsèré yí ni ó pín àwòrán yí sí orí èro ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán èyìn Chidinma Ekile tí ó rewà .
Òrò tí ó gbòde kan ni wípé Chidinma Ekile ti darapò mó egbé burúkú àti wípé ó ti n kégbékégbé látàrí wípé ó ya tàtúù dí èyìn rè . Chidinma Ekile níbi ayeye kan tí ó wo aso tí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arewà tí ó se ìgbéyàwó láì kun nkankan sí ojú ní ojó èye rè .
Èyin òdóbìnrin ; njé èyin le múra báyìí ní ijó ìgbéyàwó yín bí? Gbogbo obìnrin ni ó máa n gbèrò láti dàbí egbin ní ojó ìgbéyàwó won , gbogbo ònà ni won yóò sì wá láti jékí èróngbà won ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock.
Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock. Èyí ni àwòrán láti òdò igbákejì Ààre, professor Yemi Osinbajo, omobìnrin rè Oludamilola Osinbajo níbi ìgbéyàwó ìbílè rè èyí tí ó wáyé ní ilé Ààre orílè èdè Nàíjíríà. Igbákejì ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ọ̀jọ̀gbón Akinwunmi Isola
Ọ̀jọ̀gbón Akinwunmi Isola ni wọn bí ní ọjọ́ kẹrìnlélọ́gún oṣù Ọ̀pẹ ọdún 1939 (24 December 1939) wọn jẹ́ òsèsé, ohun kọ̀wé, Oluṣiṣẹ nípa èdè Yorùbá. A mò wón sí kíkọ ìwé ni èdè Yorùbá, wón sì tún gbé èdè Yorùbá ...
Read More »Osù ìdèra, ìtèsíwájú, ìse rere ni yóò jé fún gbogbo wa. Nínú Osù tuntun yìí, àìsàn kò níí jé ìpín enìkóòkan wa. Eni yòówù tí àìlera bá n dà láàmú, Olódùmarè yóò so ó dèrò. A kò níí rí ìjà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon ológun orílè èdè Nàíjíríà ya àwòrán pèlú ejò rògbòdò léyìn tí won pa á tán .
Àwon ikò ológun ni inú won n dùn tí won sì n yò léyìn tí won pa ejò nla rògbòdò kan níbi tí won tèdó sí . Àwon Akoni yí ya àwòrán pèlú eranko afayàfà yí nígbà tí inú ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Alágbárí òdómokùnrin kan tí a mò sí yahoo boy lo omo ègbón rè okùnrin tí kò ju omo odún méje lo láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó .
Òdómokùnrin kan ni owó àwon agbófinró tè nígbà tí ó n lo omokùnrin ègbón rè láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó. Gégé bí a se gbó, orúko òdómokùnrin tí a fi èsùn kan ni Tunde Owolabi ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.
Nígbà míràn kò ye kí á bá àwon òdómobìnrin wa tí won n’íìfé ohun ayé wí jù, nígbà tí ó jé wípé àwon àwùjo wa kò kúkú mú orí eni tí n se isé takuntakun wú. Ká sisé kára ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more