Home / Art / Àṣà Oòduà (page 22)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

alabi

Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè

Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...

Read More »
alufa

Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti

Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...

Read More »
Trump missile

Ìdí tí a fi yọ Donald Trump nípò Ààrẹ

Alágbára ayé,alágbára ayé,a sè a ṣẹ̀ má lù kan, Ọlọ́run o tíì da sí dúníyàn .Bí nǹkan se n lọ yìí, Donald Trump ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà kẹta nínú ìtàn tí ọ̀bẹ yóó bá ń dìí láti ọ̀dọ̀ àwọn Ilé ...

Read More »
customu

Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs

Awon ajo asobode ile Nigeria ti gbogbo eniyan mo si Customs ni won n ba awon oniroyin soro ni ipinle Adamawa pe, ko si ile tabi soobu ti awon ko le ja tabi fo ti o ba ye.Won ni gbogbo ...

Read More »
asia pupa

Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti

Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’EkitiYinka AlabiIdaji oni ojo kokanlelogun, osu kejila odun yii ni awon ara ilu Orin Ekiti dede de oko ti won ba Asia pupa to tumo si wi pe, ki awon ara agbegbe naa ma se ...

Read More »
seyi makinde

Ilé Ẹjọ́ Tó Ga Jù Dá Seyi Makinde Láre Gẹ́gẹ́ Bíi Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ilé ẹjọ́ tó ga jù dá Seyi Makinde láre gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀rọ̀ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lọ́wọ́-lọ́wọ́ onímọ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé tí di ọmọ oṣupa lé ẹ̀ ní kò gún,……bí Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ lórílẹ̀-èdè ...

Read More »
kini

Kini a npe eleyi ni ede kaaro o ojire?

Read More »
olori

Ìdí tí Oluwo fi kọ Olorì rẹ̀ sílẹ̀ rèé

Ìdí tí Oluwo fi kọ Olorì rẹ̀ sílẹ̀ rèé Fẹ́mi Akínṣọlá Kábíèsí Oluwo ti ìlú Ìwó, Ọba Abdulrosheed Adewale ti kọ Olorì rẹ̀ Chanel Chin sílẹ̀. Agbẹnusọ fún Kábíèsí ọ̀hún, Alli Ibrahim fi ìdí ọ̀rọ̀ náà mulẹ fún akọ̀ròyìn. Bí ...

Read More »

Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida

Aheso oro ni iku BabangidaYinka AlabiAriwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni. ...

Read More »
Èèmọ̀ rè é o , Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la

Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la

http://iroyinowuro.com.ng/2019/12/14/eemo-re-e-o-iyawo-afesona-ku-sinu-kanga-nigbeyawo-kola/ Èèmọ̀ rè é o !, Ìyàwó àfẹ́sọ́nà kú sínú Kànga, nígbeyàwó kọ̀la Fẹ́mi Akínṣọlá À fi ká kún f’áàdúà kí ọjọ́ ayọ̀ ẹni ó má padà dọjọ́ ìbànújẹ́.Kí èṣù ó sì má ráàyè gbọjọ́ ẹ̀yẹ ẹni . À bí ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb