Home / Art / Àṣà Oòduà (page 23)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

oodua

Ọrẹ Fálọmọ , Irúnmọlẹ̀ Ìṣègùn Tó Dáńtọ́ Nínú Ìràn Oòduà(Yorùbá) Wọ Káàlẹ̀ Lọ

Ọrẹ Fálọmọ , irúnmọlẹ̀ ìṣègùn tó dáńtọ́ nínú ìràn Oòduà(Yorùbá) wọ káàlẹ̀ lọ Fẹ́mi Akínṣọlá Hùn! Báakú làá dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Ni báyìí, gbogbo ọmọ Oòduà(Yorùbá) ló tí ń sun rárà ọlọ́kan ọ̀ jọ̀kan lẹ́yìn in Dókítà Ọrẹ Fálọmọ ...

Read More »
Àjọ àgùnbánirọ̀

O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC)

O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC) Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀gá àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀ lórilẹ̀-èdè Nàìjíríà, Brig. Shuaibu Ibrahim ti sàlàyé fún akọ̀ròyìn pé ààyè wà fún àgùnbánirọ̀ tó bá fẹ́ ...

Read More »

Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbààgbà Oòduà Ní Osinbajo Kò Gbọdọ̀ Kọ̀wé Fipò Ẹ̀ Sílẹ̀

http://iroyinowuro.com.ng/2019/11/09/egbe-awon-agbaagba-yoruba-ni-osinbajo-ko-gbodo-kowe-fipo-e-sile/ Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Oòduà (Yorùbá) ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Èyí ò tófò, kò tófò,fìlà aráabí kù rébété, Kemi Adeoṣun lọ , orí ló kó Adebayọ Shittu yọ,tó fi rí sáa àkọ́kọ́ lò já.Ní ...

Read More »
katoliki

Ìjọ Kátólíkì Bẹ̀rẹ̀ Ìwáàdì Lẹ̀yìn Tí Àwọn Sisitá Méjì Lóyún Ójijì

http://iroyinowuro.com.ng/2019/11/09/ijo-katoliki-bere-iwaadi-leyin-ti-awon-sisita-meji-loyun-ojiji/ Ìjọ Kátólíkì bẹ̀rẹ̀ ìwáàdì lẹ̀yìn tí àwọn sisitá méjì lóyún ójijì Fẹ́mi Akínṣọlá Eemọ̀ lukutu pẹ́bẹ́,kò síbi tí ìṣe ò sí. Ayé dojú kejì, wọ́n ń bámí ẹran níhòòdí ọmọ èèyàn. Ìjọ Kátólíìkì ti ń ṣe ìwádìí bí àwọn ...

Read More »
Governor Seyi Makinde

Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ

Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Seyi Makinde ti se àbẹ̀wò sí ilé Ọlọrẹ tó wà ní àdúgbò Ọ̀jọ́ nílùú Ibadan .Bẹ́ẹ̀ bá gbàgbé, ilé yìí ...

Read More »

N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele

N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...

Read More »
Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan si n yo ijoba ipinle Eko lenu pe ki o ti gbogbo ilu pa lo le segun arun naa daadaa. Sanwo-Olu da won lohun pe arun naa ko ti ran de iye to le mu ki ijoba ti gbogbo Eko nitori ipo ti ipinle naa wa ni orileede yii. Gomina Sanwo-Olu tun salaye awon to maa letoo si ounje ofe. O ni awon ti eya ara pe nija ati awon arugbo ni eto naa koko wa fun bayii. O ni bi agbara ba se n de sii ni o maa so bi awon se maa te siwaju nipa iranlowo naa. Bayii eniyan aadorin (70) lo ti ko arun buruku naa ti merinlelogoji (44) si sele ni ipinle Eko. Ki Eledua ba wa segun ajakale arun naa.

Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu

Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa ...

Read More »
Abiola Ajimobi

A Dúró Lójú Òpó Ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Àkọ́kọ́ Lórí Ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́

A dúró lójú òpó ìdájọ́ ilé Ẹjọ́ àkọ́kọ́ lórí ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà àná ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Abiola Ajimọbi ti fìdí rẹmi nínú ìpẹ̀jọ́ rẹ̀ láti tako ìbò tí ó gbé ojúgbà rẹ̀ Kọla Balogun wọlé gẹ́gẹ́ ...

Read More »
Àṣírí pásìtọ̀

Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú

Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...

Read More »
kano

Ayédèrú ni ‘plate number Chief Whip’ Kano – FRSC

Iroyin asise nomba moto asofin ilu Kano, Ogbeni Ayuba Durum ran kaakiri bi ina inu oye, paapaa julo lori ero ayelujara. Eyi wa ya gbogbo aye lenu pe se bee ni awon ajo FRSC tii se adari eto irinna ati ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb