Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.
Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ...
Read More »Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.
Gbajúgbajà Òsèré Yvonne Jegede Fawole àti oko rè dun nú nígbà tí won bí omo tuntun tí ó tún jé Àkóbí won. Bí ó ti lè jé wípé a kò tí mò bóyà ako ni àbí abo sùgbón a mò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ká ṣojú ẹni Ká sẹ́yìn ẹni Orúkọ tí à á pe ìránṣẹ́ (ìbò) .
Òtítọ́ wọn kò sí láyé mọ́ Aṣẹ̀yìn deni wọn kò wọpọ̀ Àbàtà ńlá abojú dẹ̀gun dẹ̀gun Ká ṣojú ẹni Ká ṣẹ̀yìn ẹni Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ọmọ ìkọ́fa Ilé Àgbọnnìrègún Baba kọ́won ní dídá ọwọ́ Wọ́n mọ̀ ọ́n dá Ifá kọ́won ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Akékòó okùnrin tí ó ti wà ní ìpelè tí ó parí ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìlú Oko ni won yìnbo fún tí ó sì kú.
Arákùnrin kan ni won yìn ìbon fún ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìjoba ní Oko ní ìpínlè Anambra. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé tí gbogbo èèyàn mò sí ‘ De moon’ jé Akékòó féè pari tí ó sì jé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.
Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú. Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won fé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Toke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.
Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù . ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour.
Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour. Gégé bí òrò ata díndín tí ó gbòde kan, òrò nípa Tiwa Savage àti Wizkid tí àwon èèyàn n gbà, tí won sì ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ogbè Ògúndá (Ogbèyọ́nú)
Ifá pé òun yóò ṣe oore òjijì fún ọmọ Ogbèyọ́nú tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún. Ifá pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò tó nǹkan nínú òun; pé kó lọ ní ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀ síwájú síi nínú òun Ọ̀rúnmìlà. Ifá ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.
Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè. Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more