Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o, bi a se njade lo loni aanu eledumare koni fiwa sile o ase. Loni mofe ki e mo dajudaju wipe Orunmila ni olugbala eda, paapajulo awa adulawo bee naa ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Orunmila Ni Olugbala Eda, Bee Naa Lo Si Tun Je Olugbala Fun Awon Irunmole Akegbe Re Naa
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o, bi a se njade lo loni aanu eledumare koni fiwa sile o ase. Loni mofe ki e mo dajudaju wipe Orunmila ni olugbala eda, paapajulo awa adulawo bee naa ...
Read More »ayangalu Comments Off on E gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,
E jiire eyin eeyan mi, e je ki a gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila, mo nki lati inu Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ), o ki bayi pe,’ Bibi inu ko da nkan, suuru ni baba Iwa, agba to ...
Read More »ayangalu Comments Off on Fi odu ifa mimo OTURUPONDI dupe oore lowo Olodumare
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku odun aku iyedun emin wa yio se pupo re laye ninu ola ati alaafia ara o ase. Mo se ni iwure laaro yi wipe gbogbo ohun ti a lelele lodun to koja lo ...
Read More »Lolade Comments Off on Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi?
Eku ise ana o, a si ku popo sinsin odun o emin wa yio se pupo loke erupe ninu alaafia ara o, bi a se njade lo loni eledumare ninu aanu re yio fi iso ati aabo re bowa lowo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ekale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?
Gbogbo eyin apapo olorire lagbaiye mini ile nla I.K.O. NLA wayi o lawujo apapo awon ojogbon awo mimo Fun idanileko Lori ASA ile wa Opolo eni kokan wa koni di oku o Ifa koni kuru lakaye eni kokan wa o ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O
Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Ojo Eti
Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa olokun adore dayo aso oro gbogbo wa di ayo ooo.
Ase !
Read More »ayangalu Comments Off on Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Toni Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more