Home / Art / Àṣà Oòduà (page 98)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Odu Ifa Owonrin Elejigbo/ Otua

| |  | | | | | |    | |    | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku imura toni, mo gbaladura wipe bi a se njade lo laaro yi aori ...

Read More »
ifa boy

Odu Owonrin Alakuko/Irete

| | | | | | | | | |   | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku imura toni o, mo gbaladura laaro yi wipe eledumare yio mu gbogbo nkan to ndena ...

Read More »
awo

Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!

A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase!   K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole

Read More »
difference Irunmole and Orisa

Orisa Alaase, Igbakeji Olodumare

Read More »
ifa verse

Odu Ifa Owonrin Alakara/ Ika

| |  | | | |   | | |   | | |   | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi alayo loni eledumare yio funwa ni isimi to peye ...

Read More »
oruko

Oruko kan fu foto yi ?

Oruko kan fu awon arakurin yii  ?

Read More »
asa yoruba

Aja To Rele Ekun To Bo..

Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...

Read More »
oriki

Oriki Ibeji

Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...

Read More »
opn ifa

Odu Ifa Owonrinwofun/ Ofun

| | | | | | | | | | | |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa ...

Read More »
osun

‪#‎CelebratingOsun‬

Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase!   Photo Cc – Bekky Amusa

Read More »

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb